Ṣàkójọ Ìjábọ̀ Titun kan |
Tọpinpin ìjábọ̀ tó wà tẹ́lẹ̀ |
Ńpèsè ìforúkọ́ pamọ́, ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ àṣírí fún àwọn ilé-iṣẹ́ káàkiri àgbáyé.
Ìlépa NAVEX ni láti ṣàrídájú pé o le sọ nípa àwọn ìṣòro àti ìrújú tó níṣe pẹ̀lú àwọn ìṣe tí kò bá òfin mu tabí tí kò dára lábẹ́ ààbò àti òtítọ́ pẹ̀lú ìṣàkóso ilé-iṣẹ́ tàbí ìgbìmọ̀ àwọn adarí tí o kò sì ní láti dárúkọ rẹ àti ààbò ohun àṣírí. NAVEX jẹ́ Ibi Ààbò tí A Jẹ́rìísí nípasẹ̀ Ẹ̀ka Iṣẹ́ Ọrọ̀ Ajé ti United States bíi olùpèsè ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀ tó ní ààbò láti dojúkọ ọgbọ́n-inú ìpamọ́ EU àti àwọn ìlànà ìpamọ́ àgbáyé míràn. A tiraka láti jẹ́ kí jíjábọ̀ ìṣòro ati ìrújú nípasẹ̀ EthicsPoint™ rọrùn kó sì jẹ́ àìrújú. Àwọn ojúlé wẹ́ẹ̀bù wọ̀nyí yóò tọ́ọ sọ́nà nípa ìlànà náà nigbàtí a kò ní dárúkọ rẹ tàbí irú ẹni tí o jẹ́ ní ìgbésẹ̀ kọ̀ọ̀kan. Tẹ̀lé àwọn ìgbésẹ̀ wọ̀nyí láti fa ìjábọ̀ rẹ kalẹ̀:
Lẹ́yìn tí o bá fa ìjábọ̀ rẹ kalẹ̀, a ó fún ọ ní kọ́kọ́rọ́ ìjábọ̀ kan. Ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ àti kọ́kọ́rọ́ ìjábọ̀ ń gbà ọ́ láàyè láti tọpinpin ìjábọ̀ rẹ. |